Kí Òrìsà-nlá Olú àtélesé, a gbénon dídùn là.
Ní Ibodè Yìí, Kò Sí Òsán, Bèéni Kò Sí Òru.
Kò Sí Òtútù, Bèéni Kò Sí Ooru.
Ohun Àsírií Kan Kò Sí Ní Ibodè Yìí.
Gbogbo Dúró Kedere Nínu Ìmólè Olóòrun.
Àyànmó Kò Gbó Oògùn. Àkúnlèyàn Òun Ní Àdáyébá.
Àdáyébá Ni Àdáyé Se.
Nenhum comentário:
Postar um comentário